​*TANI ODUDUWA*

 HMMM AWO FASINA OLOSA JOLAOGUN,AWOTUNDE JOLAOGUN MOSE IBA GBOGBO EYIN AGBA ATI GBOGBO OMODE AYE LONI OO NITORI A DOKO MAJUBA O SE ARARE NI NKAN AGBE TO DOKO TIO JUBA FUN ILE ERUPE NI YIO FO AGBE LOJU KOTO DI OJO ALE HMM TA GAN NI AN PENI ODUDUWA SE BI BI A BA PE ORI AKONI NISE NI AO FI IDA HALE GARAGA ITAN MEJI PATAKI NI O SORO NIPA ENITI ODUDUWA JE ITAN AKOKO SOPE ODUDUWA WA GBA ISE TI OLODUMARE KOKO RAN OBATALA NI PE O SI MU AWON NKAN MAARUN WA LARA WON NI EWON TIO FI RO WA TI WON FI MA NKI NI OODUA ATEWON RAN EKEJI ADIE TIO BA TAN YEPE KA ILE TI ILE GBIGBE FI JADE EKERIN IGBA ATI ALAGEMO TOFI YE ILE WO BOWA O TI SE DADA ITAN YI JE KA MO ME ODUDUWA KI SE BABA NLA YORUBA NIKAN PE BABA NLA GBOGBO AYE NI ILE IFE SINI ORIRUN GBOGBO AYE KII SE ORIRUN YORUBA NIKAN TORI IBE NI ODUDUWA KOKO TEWON WO HMMM MO SOYI MO DURO NAA ASOJU ORO LO PA ELENPE AKOKO ENU MI AGO KENU MASE PAMI E PADE MI NI APAKEJI PELU ITAN KEJI IBITI ODUDUWA TI SE WA EMI TOLOHUNLASE OMO OODUA BABA AKANLO EDE YIN NAA NI EYONU SIMI OOOOOO EKU OJU LONA

CATEGORIES
TAGS
Share This

COMMENTS

Disqus ( )