​*ITAN ODUDUWA APAKEJI*

 HMM TOLOHUNLASE TUN DE BIO SE MA NDE ONILE MO KA AGO NITORI EWURE TO WOLE TIO KI AGO NI O DI ERAN AMUSO EDUMARE MAJE KI TEMI TIYIN O DI ERAN AMUSO HMM SE BI SEKERE KO DEDE DUN ILEKE LOSE SABABI RE BI MO BA N SO EWA EDE,ITAN TABI OWE HMM IBA OGA MI ADEJUMO OMO WON LOSOSBO OROKI NILE ALABA ENI BA NLO SI SABO SI ATELEWO KIO BAMI YAKI OGA MI ATI ABILEKO ADELOWO SE BI IBITI ABA RO OKO TI SI NI A MA NFI ABO SI AWON APAKEJI ITAN JE KIO YE WA PE ILU MECCA NI LAMURUDU TIO JE BABA ODUDUWA WA TIO SIJE OLORI AWON ABORISA KAN IGBATI IJA ESIN MUSULUMI BEERE NI WO PA LAMURUDU TI ODUDUWA SIGBE OKAN LARA ORISA TIO NI AGBARA WA SI ILE IFE ODUDUWA BA OPOLOPO AWON EDA NI ILE IFE SUGBON PELU OGBON ATI AGBARA RE O BORI GBOGBO WON WON SI TERI BA FUN NI ARA AWON TIO BA NI OBATALA ORISIRISI NI IJA TIO WAYE NI ARIN WON SUGBON MO BO WA PELU ALAAYE LEKUN RERE E KU OJU LONA

CATEGORIES
TAGS
Share This

COMMENTS

Disqus ( )