ITAN BASORUN OLUYOLE APAKINNI

ITAN BASORUN OLUYOLE APAKINNI
HMMM TOLOHUNLASE TUN DE OMO OODUA PELU AWON ITAN ILE YORUBA OTITO OMODE NIMI A MO BIOMODE KO BA BA ITAN YIO BA AROBA OUN TI MO FE KI A MO NIPE GBOGBO ITAN TI AUN SO NINU IKANNI YI GELE BIO SE RI NIYEN NITORI BIO SELE WU KI OKUN GUN TO OGBODO NI IBITI O TI SEWA AO MA TUWA KAN ARAWA NI OMO OODUA OKAN NI GBOGBO WA
HMM OLUYOLE JE OMO AGBORIN TI AGBOIN JE OMO OBA ABIODUN AGBOLUAJE ALAAFIN TI GAA FI SE ETUTU OWO NI OJO SI BASORUN OLUYOLE NIKAN NIO BI AWON ISELE KAN LOSELE TI O FI DI ALAINI ENIKAN MO EYI LOMU MURA GIDI LATI DI ENI NLA GBOGBO IWA BI KALONI LOWO GBA ORISIRISI IWA BUBURU NIO WA NI OWO RE KAJAGUN GBA ILE GBALE EYI NIO SE DE ILU IBADAN TIO SI BA AWON ALAGBARA KAN NI IBE SUGBON PELU OGBON ATI AGBARA WON PADA TERI BA FUN HMMM AWON ISE TO SE NI IBADAN KONI AFI WE BEENI KOSE GBAGBE E PADE MI NI APAKEJI KIUN TO MA TUN PEREPERE ITAN IGBESI AYE RE IBA OLOHUN ATI GBOGBO EYIN OMODE PELU AGBA EYONU SIMI TORI ERIN NI AGBARA MA NRIN KO ODO LONA OMO TUNTUN NI TOLOHUNLASE OTOLORIN E MA GBEMI GEGE GBEMI JO NITI AYO
E KU OJU LONA OOOO

CATEGORIES
TAGS
Share This

COMMENTS

Disqus ( )