​ITAN BASORUN OLUYOLE APAKETA

ITAN BASORUN OLUYOLE APAKETA

 HMMMM TOLOHUNLASE NI MO WU EEDUA ABURU KANKAN KONI KOLU EMI ATI EYIN OOO HMMM BI A SE NBA LO NINU APAKEJI OLUYOLE NPASE NI IBADAN TIO TI JE IBA IBADAN IWA BURUKU RE N POSI BE SI NI OUN WU IWA AASO KOFE ALAGBARA KAN KAN TUN WA NI IBADAN YA TO DI OUN GBOGBO AWON ALAGBARA TOWA NI ILU IBADAN NI O FI OGBON RAN LO OGUN TIO SE FI OFFA TO SE SI WON NI APO TI WON KO FI LE SEGUN TIWON KU SI OJU OGUN AWON MIIRAN TILE WA TIO SEPE O FI ETAN PAWON FUN RARE NI AWON ASE OGUN TAN A TUN WA OMIIRAN FUN WON LAI NI IDI KAN PATO SUGBON TI A BA  YOO TI IWA AFI EMI OLUYOLE O SE AWON ISE RERE KOOKAN ASIKO RE NI ILU IBADAN NFE SI NITORI A MA JAGUN GBA ILE ONILE FUN IBADAN

[6/6, 2:26 AM] ‪+234 703 562 7411‬: KODA ASIKO RE NI OJA IBA TI AWON ENIYAN N MA N SII PE NI OJA OBA GBOORO SI O TIPE TI OLUYOLE TIUN WO IWA YI NI AWON ALAGBARA TOKU NAA BEERE ETE LATI RI EYIN OLUYOLE KOTO PA GBOGBO WON TAN WON RANSE SI ALAGBARA KAN LATI OYO ALAAFIN KI ALAGBARA NAA TO DE OLUYOLE TI MO NITORI ORE MIINU RE NI ELEEPO TI SOFUN O SI TI KE TAKUTE IKU LE FUN SUGBON OLOHUN YOO KO RIN ONA NAA A MA KO RI AAYE ATI DE ILE OLUYOLE NI O BA BEERE ABULU ATI EPE SI ILE OLUYOLE KIO TO FI ILU IBADAN SILE NI OJO KEJI TI ALAGBARA YI LO NI OLUYOLE N GUN ESIN LO

[6/6, 2:33 AM] ‪+234 703 562 7411‬: OSI SUBU LORI ESIN O DA NI APA ATI ESE EYI KOJE KIO LE DIDE MO KODA WON BEERE SINI FI SE YEYE KOSI RI NKAN SESI TITI O FI KU HMMM IBA OLOHUN OUN NIKAN NI AASO TIO PE MEJI OBA TI KII LENI KO TO MUNI EYI SINI OLUYOLE ALAGBARA BA LO KAA ILE HMM AGBARA WO LONI TIUN GUN OO KOTO TI OLUYOLE TI AGBARA RE IKU YEYE LOPA OLOHUN MA DE IGBARAGA SIWA KI A MA SE PARUN LOJIJI HMMM ABO MI RE OOO TOLOHUNLASE OMO OODUA BABA AKANLO EDE TONI EMI NI MA MA WA EYIN NI MA MA BA IKU KONI PA EMI TEYIN AISA KI YIO PE WA DE ASE OODUA E TUN KU OJU LONA AKOTUN ITAN ILE YORUBA MIIRAN OOOOO

IBA EYIN AGBA

[6/6, 2:39 AM] ‪+234 703 562 7411‬: OSI SUBU LORI ESIN O DA NI APA ATI ESE EYI KOJE KIO LE DIDE MO KODA WON BEERE SINI FI SE YEYE KOSI RI NKAN SESI TITI O FI KU HMMM IBA OLOHUN OUN NIKAN NI AASO TIO PE MEJI OBA TI KII LENI KO TO MUNI EYI SINI OLUYOLE ALAGBARA BA LO KAA ILE HMM AGBARA WO LONI TIUN GUN OO KOTO TI OLUYOLE TI AGBARA RE IKU YEYE LOPA OLOHUN MA DE IGBARAGA SIWA KI A MA SE PARUN LOJIJI HMMM ABO MI RE OOO TOLOHUNLASE OMO OODUA BABA AKANLO EDE TONI EMI NI MA MA WA EYIN NI MA MA BA IKU KONI PA EMI TEYIN AISA KI YIO PE WA DE ASE OODUA E TUN KU OJU LONA AKOTUN ITAN ILE YORUBA MIIRAN OOOOO

IBA EYIN AGBA

CATEGORIES
TAGS
Share This